Àìsáyà 49:20 BMY

20 Àwọn ọmọ tí a bí ní àkókò ọ̀fọ̀ rẹyóò sọ ní etígbọ̀ọ́ rẹ,‘Ibi yìí ti kéré jù fún wa;ẹ fún wa láyè sí i tí a ó máa gbé.’

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:20 ni o tọ