Àìsáyà 5:11 BMY

11 Ègbé ni fún àwọn tí wọ́n dìdení kùtùkùtù òwúrọ̀láti lépa ọtí líle,tí wọ́n sì mu ún títí alẹ́ fi lẹ́títí wọ́n fi gbinájẹ pẹ̀lú wáìnì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:11 ni o tọ