Àìsáyà 5:12 BMY

12 Wọ́n ní hápù àti láà níbi àṣè wọn,tamborínìn òun fèrè àti wáìnì,ṣùgbọ́n wọn kò ka iṣẹ́ Olúwa sí,kò sí ìbọ̀wọ̀ fún iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:12 ni o tọ