Àìsáyà 51:14 BMY

14 Àwọn ẹlẹ́wọ̀n tí ń ṣojo la ó dá sílẹ̀ ní àìpẹ́ jọjọwọn kò ní kú sínú túbú wọn,bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ní ṣe aláìní àkàrà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 51

Wo Àìsáyà 51:14 ni o tọ