Àìsáyà 51:4 BMY

4 “Tẹ́tí sími, ẹ̀yin ènìyàn mi;gbọ́ tèmi, ẹ̀yin orílẹ̀ èdè mi:Òfin yóò ti ọ̀dọ̀ mi jáde wá;ìdájọ́ mi yóò di ìmọ́lẹ̀ sí àwọn orílẹ̀ èdè.

Ka pipe ipin Àìsáyà 51

Wo Àìsáyà 51:4 ni o tọ