Àìsáyà 51:5 BMY

5 Òdodo mi ń bọ̀ wá kíkankíkan,ìgbàlà mi ń bọ̀ lójú ọ̀nà,àti apá mi yóò sì mú ìdájọ́ wásí àwọn orílẹ̀ èdè.Àwọn erékùṣù yóò wò míwọn yóò sì dúró ní ìrètí fún apá mi.

Ka pipe ipin Àìsáyà 51

Wo Àìsáyà 51:5 ni o tọ