Àìsáyà 51:7 BMY

7 “Ẹ gbọ́ mi, ẹ̀yin tí ó mọ ohun tótọ́,ẹ̀yin ènìyàn tí ó ní òfin mi ní àyàa yín:Ẹ má ṣe bẹ̀rù ẹ̀gàn àwọn ènìyàntàbí kí ẹ̀rù èébú wọn já a yín láyà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 51

Wo Àìsáyà 51:7 ni o tọ