Àìsáyà 51:8 BMY

8 Nítorí kòkòrò yóò mú wọn lá bí aṣọ;Ìdin yóò sì mú wọn jẹ bí Ẹ̀gbọ̀n òwú.Ṣùgbọ́n òdodo mi yóò wà títí ayérayé,àti ìgbàlà mi láti ìrandíran.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 51

Wo Àìsáyà 51:8 ni o tọ