Àìsáyà 51:9 BMY

9 Dìde, dìde! Kí o sì wọ ara rẹ ní agbáraÌwọ apá Olúwa;dìde gẹ́gẹ́ bí i ti ọjọ́ ìgbà n nì,àti gẹ́gẹ́ bí i ti ìran àtijọ́.Ìwọ kọ́ lo ké Rékábù sí wẹ́wẹ́tí o sì fa ewèlè yẹn ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ?

Ka pipe ipin Àìsáyà 51

Wo Àìsáyà 51:9 ni o tọ