Àìsáyà 53:10 BMY

10 Ṣíbẹ̀, ó wu Olúwa láti pa á láraàti láti mú kí ó jìyà,bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Olúwa fi ayé rẹ̀fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀,Òun yóò rí àrọ́mọdọ́mọ rẹ̀ àti ọjọ́ ayérẹ̀ yóò pẹ́ títí,àti ète Olúwa ni yóò gbèrú ní ọwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 53

Wo Àìsáyà 53:10 ni o tọ