Àìsáyà 53:5 BMY

5 Ṣùgbọ́n a ṣá a lọ́gbẹ́ nítorí àìṣedédé waa pa á lára nítorí àìsòdodo wa;ìjìyà tí ó mú àlàáfíà wá fún wa wà lóríi rẹ̀,àti nípa ọgbẹ́ rẹ̀ ni a fi múwa láradá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 53

Wo Àìsáyà 53:5 ni o tọ