Àìsáyà 53:6 BMY

6 Gbogbo wa bí àgùntàn, ti sìnà lọ,ẹnìkọ̀ọ̀kan wa ti yà sí ọ̀nà ara rẹ̀; Olúwa sì ti gbé e ka orí ara rẹ̀gbogbo àìṣedédé wa.

Ka pipe ipin Àìsáyà 53

Wo Àìsáyà 53:6 ni o tọ