Àìsáyà 59:13 BMY

13 ọ̀tẹ̀ àti àrékérekè wa sí Olúwa,kíkọ ẹ̀yìn wa sí Ọlọ́run,dídá yánpọnyánrin àti ìnilára sílẹ̀,pípààrọ̀ tí ọkàn wa ti gbérò síta.

Ka pipe ipin Àìsáyà 59

Wo Àìsáyà 59:13 ni o tọ