Àìsáyà 61:3 BMY

3 àti láti pèṣè fún àwọn tí inú wọn bàjẹ́ ní Ṣíhónìláti dé wọn ládé ẹ̀yẹ dípò eérú,òróró ìdùnnú dípò ìbànújẹ́,àti aṣọ ìyìn dípò ìpòrúùru ọkàn.A ó sì pè wọ́n ní óákù òdodo,irúgbìn Olúwaláti fi ọláńlá rẹ̀ hàn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 61

Wo Àìsáyà 61:3 ni o tọ