Àìsáyà 61:4 BMY

4 Wọn yóò tún àwọn ahoro ìṣẹ̀ǹbáyé kọ́wọn yóò sì mú àwọn ibi ìparun àtijọ́tijọ́ náà bọ̀ sípò;wọn yóò jí àwọn ahoro ìlú náà padàtí a ti parun láti ìrandíran sẹ́yìn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 61

Wo Àìsáyà 61:4 ni o tọ