Àìsáyà 61:6 BMY

6 A ó sì máa pè yín ní àlùfáà Olúwa,a ó pè yín ní ìránṣẹ́ Ọlọ́run wa.Ẹ ó máa jẹ nínú ọrọ̀ àwọn orílẹ̀ èdèàti nínú ọrọ̀ wọn ni ẹ̀yin yóò máa ṣògo.

Ka pipe ipin Àìsáyà 61

Wo Àìsáyà 61:6 ni o tọ