Àìsáyà 61:7 BMY

7 Dípò àbùkù wọnàwọn ènìyàn mi yóò gba ìlọ́po-méjì,àti dípò àbùkù wọnwọn yóò yọ̀ nínú ìníi wọn;bẹ́ẹ̀ ni wọn yóò sì jogún ìlọ́po méjì ní ilẹ̀ wọn,ayọ̀ ayérayé yóò sì jẹ́ ti wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 61

Wo Àìsáyà 61:7 ni o tọ