Àìsáyà 61:8 BMY

8 “Nítorí Èmi, Olúwa fẹ́ràn ìdájọ́ òdodo;mo kórìíra olè jíjà àti ẹ̀ṣẹ̀Ní òtítọ́ mi èmi yóò ṣẹ̀san fún wọnèmi yóò sì dá májẹ̀mú ayérayé pẹ̀lúu wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 61

Wo Àìsáyà 61:8 ni o tọ