Àìsáyà 62:9 BMY

9 ṣùgbọ́n àwọn tí ó bá kóórè rẹ̀ ni yóò jẹ ẹ́tí wọn ó sì yin Olúwa,àti àwọn tí wọ́n bá kó gírépù jọ ni wọn ó mú unnínú àgbàlá ilé mímọ́ mi.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 62

Wo Àìsáyà 62:9 ni o tọ