Àìsáyà 63:16 BMY

16 Ṣùgbọ́n ìwọ ni Baba wa,bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Ábúráhámù kò mọ̀ wátàbí Ísírẹ́lì mọ ẹni tí à á ṣe;ìwọ, Olúwa ni Baba wa,Olùràpadà wa láti ìgbà n nì ni orúkọ rẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 63

Wo Àìsáyà 63:16 ni o tọ