Àìsáyà 63:15 BMY

15 Bojúwolẹ̀ láti ọ̀run kí o sì rí iláti ìtẹ́ ògo rẹ, mímọ́ àti ológo.Níbo ni ipá àti agbára rẹ wà?Ìwà jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ rẹ àti àánú rẹ ni atí mú kúrò níwájúu wa.

Ka pipe ipin Àìsáyà 63

Wo Àìsáyà 63:15 ni o tọ