Àìsáyà 63:14 BMY

14 gẹ́gẹ́ bí ọ̀wọ́ ẹran tí ó lọ sí pápá oko,a fún wọn ní ìsinmi láti ọwọ́ Ẹ̀mí Olúwa.Báyìí ni ẹ ṣe tọ́ àwọn ènìyàn yínláti fún ara yín ní orúkọ kan tí ó lógo.

Ka pipe ipin Àìsáyà 63

Wo Àìsáyà 63:14 ni o tọ