Àìsáyà 64:12 BMY

12 Lẹ́yìn gbogbo nǹkan wọ̀nyí, Olúwa, ìwọó ha sì tún fara rẹ pamọ́ bí?Ìwọ ó ha dákẹ́ kí o sì fìyà jẹwá kọjá ààlà bí?

Ka pipe ipin Àìsáyà 64

Wo Àìsáyà 64:12 ni o tọ