Àìsáyà 65:1 BMY

1 “Èmi fi ara mi hàn fún àwọn tí kò béèrè fún mi;Àwọn tí kò wá mi ni wọ́n rí mi.Sí àwọn orílẹ̀ èdè tí kò pe orúkọ mi,Ni èmi wí pé, ‘Èmi nìyìí, Èmi nìyìí.’

Ka pipe ipin Àìsáyà 65

Wo Àìsáyà 65:1 ni o tọ