Àìsáyà 65:12 BMY

12 Èmi yóò yà ọ́ ṣọ́tọ̀ fún idà,àti pé ẹ̀yin yóò bẹ̀rẹ̀ mọ́lẹ̀ fún àwọn tí a pa;nítorí mo pè, ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò dáhùn.Mo ṣọ̀rọ̀ ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò tẹ́tísílẹ̀Ẹ̀yin ṣe búrurú ní ojú miẹ sì yan ohun tí ó bàmí lọ́kàn jẹ́.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 65

Wo Àìsáyà 65:12 ni o tọ