Àìsáyà 65:13 BMY

13 Nítorí náà ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí nìyìí:“Àwọn ìránṣẹ́ mi yóò jẹun;ṣùgbọ́n ebi yóò máa pa ẹ̀yin,àwọn ìránṣẹ́ mi yóò mu,ṣùgbọ́n òrùngbẹ yóò máa gbẹ ẹ̀yin;àwọn ìránṣẹ́ mi yóò ṣe àjọyọ̀,ṣùgbọ́n a ó dójú ti ẹ̀yin.

Ka pipe ipin Àìsáyà 65

Wo Àìsáyà 65:13 ni o tọ