Àìsáyà 65:14 BMY

14 Àwọn ìránṣẹ́ mi yóò kọrinláti inú ayọ̀ ọkàn wọn wá,ṣùgbọ́n ẹ̀yin yóò kígbe sókèláti inú ìrora ọkàn yínàti ìpohùnréré ní ìròbìnújẹ́ ọkàn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 65

Wo Àìsáyà 65:14 ni o tọ