22 Wọn kì yóò kọ́ ilé fún ẹlòmìíràn láti gbé,tàbí kí wọn gbìn fún ẹlòmìíràn láti jẹ,Nítorí gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ orí igi kan,bẹ́ẹ̀ ní ọjọ́ àwọn ènìyàn mi yóò rí;àwọn àyànfẹ́ mi yóò jẹ iṣẹ́ ọwọ́wọn fún ìgbà pípẹ́.
Ka pipe ipin Àìsáyà 65
Wo Àìsáyà 65:22 ni o tọ