Àìsáyà 65:23 BMY

23 Wọn kì yóò ṣe wàhálà lásántàbí kí wọn bímọ tí ọjọ́ iwájú wọnkì yóò sunwọ̀n;nítorí wọn yóò jẹ́ àwọn ènìyàn ti Olúwa bùkún fún,àwọn àti àwọn ìrandíran wọn pẹ̀lú wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 65

Wo Àìsáyà 65:23 ni o tọ