Àìsáyà 7:18 BMY

18 Ní ọjọ́ náà ni Olúwa yóò súfèé pe àwọn eṣinṣin láti àwọn odò tó jìnnà ní Éjíbítì wá, àti fún àwọn oyin láti ilẹ̀ Áṣíríà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 7

Wo Àìsáyà 7:18 ni o tọ