Job 1:21 YCE

21 Wipe, Nihoho ni mo ti inu iya mi jade wá, nihoho ni emi o si tun pada lọ sibẹ: Oluwa fifunni Oluwa si gbà lọ, ibukun li orukọ Oluwa.

Ka pipe ipin Job 1

Wo Job 1:21 ni o tọ