Job 10:15 YCE

15 Bi mo ba ṣe ẹni-buburu, egbé ni fun mi! bi mo ba si ṣe ẹni-rere, bẹ̃li emi kò si le igbe ori mi soke. Emi damu, mo si wo ipọnju mi.

Ka pipe ipin Job 10

Wo Job 10:15 ni o tọ