Job 20:10 YCE

10 Awọn ọmọ rẹ̀ yio ma wá ati ri oju-rere lọdọ talaka, ọwọ rẹ̀ yio si kó ẹrù wọn pada.

Ka pipe ipin Job 20

Wo Job 20:10 ni o tọ