Job 33:26 YCE

26 O gbadura sọdọ Ọlọrun, on o si ṣe oju rere si i, o si mu enia ri oju rẹ̀ pẹlu ayọ̀, on o san ododo rẹ̀ pada fun enia.

Ka pipe ipin Job 33

Wo Job 33:26 ni o tọ