Job 34:19 YCE

19 Ambọtori fun ẹniti kì iṣojuṣaju awọn ọmọ-alade, tabi ti kò kà ọlọrọ̀ si jù talaka lọ, nitoripe iṣẹ ọwọ rẹ̀ ni gbogbo wọn iṣe.

Ka pipe ipin Job 34

Wo Job 34:19 ni o tọ