Job 5:26 YCE

26 Iwọ o wọ isa-okú rẹ lọ li ògbologbo ọjọ bi apo-ọka ti o gbó, ti a si nko ni igbà ikore rẹ̀.

Ka pipe ipin Job 5

Wo Job 5:26 ni o tọ