Isikiẹli 1:22 BM

22 Kinní kan bí awọsanma tí ó ń dán bíi Kristali wà lórí àwọn ẹ̀dá alààyè náà, ó tàn bo gbogbo orí wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 1

Wo Isikiẹli 1:22 ni o tọ