Isikiẹli 10:1 BM

1 Lẹ́yìn náà, mo wo orí àwọn Kerubu, mo rí kinní kan róbótó róbótó, wọ́n dàbí òkúta safire, ìrísí wọn dàbí ìtẹ́.

Ka pipe ipin Isikiẹli 10

Wo Isikiẹli 10:1 ni o tọ