Isikiẹli 10:3 BM

3 Ìhà gúsù ilé náà ni àwọn Kerubu dúró sí nígbà tí ọkunrin náà wọlé, ìkùukùu sì bo àgbàlá ààrin ilé náà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 10

Wo Isikiẹli 10:3 ni o tọ