Isikiẹli 11:17 BM

17 “Nítorí náà, wí fún wọn pé èmi, ‘OLUWA Ọlọrun ní n óo kó wọn jọ láti ààrin àwọn ẹ̀yà ati orílẹ̀-èdè mìíràn tí mo fọ́n wọn ká sí, n óo sì fún wọn ní ilẹ̀ Israẹli.’

Ka pipe ipin Isikiẹli 11

Wo Isikiẹli 11:17 ni o tọ