Isikiẹli 11:20 BM

20 kí wọ́n lè máa rìn ninu ìlànà mi, kí wọ́n sì lè máa pa òfin mi mọ́. Wọn óo jẹ́ eniyan mi, èmi náà óo sì jẹ́ Ọlọrun wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 11

Wo Isikiẹli 11:20 ni o tọ