Isikiẹli 11:22 BM

22 Lẹ́yìn náà, àwọn Kerubu bá gbéra, wọ́n fò, pẹlu àgbá, ní ẹ̀gbẹ̀ẹ̀gbẹ́ wọn; ìtànṣán ògo OLUWA Ọlọrun Israẹli sì wà lórí wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 11

Wo Isikiẹli 11:22 ni o tọ