Isikiẹli 12:10 BM

10 Wí fún wọn pé, ‘Èmi OLUWA Ọlọrun sọ pé àsọtẹ́lẹ̀ yìí ń bá àwọn olórí Jerusalẹmu ati àwọn eniyan Israẹli tí ó kù ninu rẹ̀ wí.’

Ka pipe ipin Isikiẹli 12

Wo Isikiẹli 12:10 ni o tọ