Isikiẹli 12:15 BM

15 “Wọn óo mọ̀ pé èmi ni OLUWA, nígbà tí mo bá fọ́n wọn ká sí ààrin àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, tí mo tú wọn ká sórí ilẹ̀ ayé.

Ka pipe ipin Isikiẹli 12

Wo Isikiẹli 12:15 ni o tọ