Isikiẹli 13:15 BM

15 “Bẹ́ẹ̀ ni n óo ṣe tẹ́ ibinu mi lọ́rùn lára odi náà ati àwọn tí wọn ń kùn ún lẹ́fun. N óo wí fun yín pé, odi kò sí mọ́, àwọn tí wọn ń kùn ún lẹ́fun náà kò sì sí mọ́;

Ka pipe ipin Isikiẹli 13

Wo Isikiẹli 13:15 ni o tọ