Isikiẹli 13:23 BM

23 Nítorí náà, ẹ kò ní ríran èké mọ́, ẹ kò sì ní woṣẹ́ mọ́. N óo gba àwọn eniyan mi lọ́wọ́ yín, nígbà náà, ni ẹ óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 13

Wo Isikiẹli 13:23 ni o tọ