Isikiẹli 16:15 BM

15 “Ṣugbọn o gbójú lé ẹwà rẹ; o di alágbèrè ẹ̀sìn nítorí òkìkí rẹ, o sì ń bá gbogbo àwọn eniyan tí wọn ń kọjá ṣe àgbèrè.

Ka pipe ipin Isikiẹli 16

Wo Isikiẹli 16:15 ni o tọ