Isikiẹli 16:28 BM

28 “O bá àwọn ará Asiria ṣe àgbèrè ẹ̀sìn pẹlu, nítorí pé o kò ní ìtẹ́lọ́rùn sibẹ, lẹ́yìn gbogbo àgbèrè tí o ṣe pẹlu wọn, o kò ní ìtẹ́lọ́rùn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 16

Wo Isikiẹli 16:28 ni o tọ