Isikiẹli 17:13 BM

13 Ó mú ọ̀kan ninu àwọn ìdílé ọba, ó bá a dá majẹmu, ó sì mú kí ó búra. Ó ti kọ́ kó gbogbo àwọn eniyan pataki pataki ilẹ̀ náà lọ,

Ka pipe ipin Isikiẹli 17

Wo Isikiẹli 17:13 ni o tọ