Isikiẹli 17:18 BM

18 Kò ní sá àsálà, nítorí pé kò náání ìbúra ó sì da majẹmu, ati pé ó ti tọwọ́ bọ ìwé, sibẹsibẹ, ó tún ṣe gbogbo nǹkan tí ó ṣe.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 17

Wo Isikiẹli 17:18 ni o tọ